Evang. Victoria Adewunmi Adegoke – Oluwa Ti se
Oluwa Ti se By Evang. Victoria Adewunmi Adegoke Mp3 Download
Nigerian gospel singer, Lady Evang. Victoria Adewunmi Adegoke, releases a new single titled: “Oluwa Tise” in Yoruba language, meaning, “God has done it”.
“Oluwa Tise” is a danceable Yoruba folks song. The fascinating blend of various Yoruba percussions and a well organized strings arrangement will set you in a dance mood.
This great song was produced by the prolific, George Daniel.
Victoria Adewunmi Adegoke is a woman of faith and a preacher of the word. She currently serves as an Evangelist and head of music department, Christ Apostolic Church, Rock Of Heaven, Ita – Baale, Adigbe, Abeokuta, Ogun State, Nigeria.
She is a teacher by profession, serving in the Ogun State Teaching Service Commission. She’s also an entrepreneur, a wife and a mother.
Victoria Adewunmi Adegoke hails from Igboora, Ibarapa Central Local Government, Ogun State, Nigeria.
Lyrics Of Oluwa Ti se By Evang. Victoria Adewunmi Adegoke
Chorus:
Oluwa ti se, ara e ba mi yo
O doju telegan, mo wa fope fun o/2x
Edumare soro mi dayo
O gbe mi leke, o ra mi pada
mo wa fope fun o
O da mi si o, O yan mi fe o
O n basiri mi o, ope ye o oe
Chorus
Ayo igbala kunnu aye mi
O kunnu okan mi
Orisun ayo mi ma ni Jesu Kristi o
Mo n jola Jesu, ogo re bo mi o
Emi mimo o se to gbe mi ro oe.
Chorus
Emi mimo to ra mi pada
Lowo Egun ofin o
Emi yin o o ope ye Daddy mi o
O gbogun esu mi
O gbogun ota mi
O tun gbogun iku mi
O wa fun mi layo to po
Chorus 2:
Edumare lo ba mi se
Mo wa fope mi han
Atonigba Baba Alaanu mi
O Faye mi dara loju awon ota mi
O tun aye mi se o
Ipe mi di mimo se o
Oun aye so po ti tan o
BABA se e yori o
Eyi lo mu mi yo
Mo wa yin Jesu mi o
Chorus 2: /4x
Interval
SONG 2
Chorus:
Owo kan Kan mi
To gbe mi dide lori eekun mi
Owo to Kan mi lo gbe mi sare
Ogo mi n sare, ogo mi n fo/2x
Owo to Kan mi, lo fa mi jade
Ninu ogun, o gbokan mi la
Owo ibukun, owo ojurere
Lo wa mi ri, mo deniyan otun
Chorus
Owo to Kan mi, lo megan mi kuro
O nomije mi nu, o wo mi laso eye Owo anu lowo to Kan mi
O so mi dayanfe
Mo deniyan otun
Chorus
Owo to Kan mi, owo irapada ni
O ra mi pada lowo Ogun esu
O feje re we mi, o so mi dominira Jesu o se, to gba mi lagbatan
Chorus
Owo to Kan mi, owo Ire
Owo to Kan mi, owo ayo
Owo to Kan mi, owo aseyori
Ire mi de, itura de /2x
Ire mi de, itura de/2x Repeat
Owo to Kan mi, owo ayo
Owo to Kan mi, owo aseyori
Ire mi de, itura de
Owo to Kan mi, owo Ire
Owo to Kan mi, owo ayo
Owo to Kan mi, owo aseyori
Ire mi de, itura de
Chorus/2x
Socail Media Handle
Facebook: Victoria Adegoke
WhatsApp: +2348024113363.