Welcome to PraiseZion


NEED PRAYER/COUNSELING? CLICK HERE

PROMOTED!!!
 

Tope Alabi – Kabiyesi

Posted by: || Categories: Latest Release, Music

Advert link

Kabiyesi by Tope Alabi  Mp3 Download

Download this track from Tope Alabi titled Kabiyesi. Tope Alabi in Ogun, a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu

Use this link below to stream and download the track

Lyrics Of Kabiyesi by Tope Alabi

Ká bí o si o, mo júbà rẹOṣù bá rẹ, gbọmọ-gbọmọ lo ń roMo ki o ti’lu, ti dídún o, Ọba tọ ní míÌbá rẹ o, Ọba áńgẹ’lì (Ọba to lòun gbogbo, tòun ṣẹ òun gbobo)
Kabiyesi oo, mo júbà rẹ (ehn, ehn, ehn)Àdá ní pe (adá ní pe), à dá ní dáÀpá ńlá tó so aiye’ ro o, mo júbà rẹ (mo júbà rẹ o)Ìbá re o, mo wá rí
Gbogbo ipá, gbogbo àgbàráỌrọ godo ganya, àṣírí ọrun pẹlu aiye’Ko mámá s’àfi we rẹ o, ibà o (ko s’àfi we rẹ o, ibà o)Ọrọ ńlá to f’ọrọ dà ayé ọrunÈémí inú rẹ lo mí samo, to d’ènìyànAṣẹ̀dá Ọba ‘lú ọrùn o, tótó (tótó ọlá rẹ, ibà)
Kabiyesi o, mo júbà rẹ (ipá ńlá to borí gbogbo ipa, ehn-ehn)Àdá ní pe (adá ní pe), à dá ní dá (à dá ní dá o)Àpá ńlá to so aiye’ ro o, mo júbà rẹ (mo júbà rẹ o)Ìbá rẹ o, mo wá rí
Mo rí bá, mo ri ibà, Ọba ọrunAkọda, Aṣẹ̀dá, àdììtú ní oO dà ‘yé dà, ó dà òun gbogboÀláṣẹ lórí ikú àti abeti lukaraÌwọ lọrọ ìkòkò, ní gbangba lo wá oAyé a kọjá, ọrun a kọjá lọÌtẹ’ rẹ lọrun kíiṣí, ní gbo ta o le rọ l’óyeArọ méta tí o d’ọbẹ’ nu, tọ dúró wá mú (o dúró wá mu)
Kabiyesi oo (wámú-wamu), mo júbà rẹ (ah)Àdá ní pe, à dá ní dá (òkè tógá ti o le ja bọ láì-láì)Àpá ńlá tó so aiye’ ro o, mo júbà rẹ (ipa ńlá to so ilé ayé ro)Ìbá re o, (mo wá rí o) mo wá rí
Kabiyesi oo (Bàbá, Bàbá) mo júbà rẹÀdá ní pe (alágbára gíga), à dá ní dá (ahh)Àpá ńlá tó so aiye’ ro o, mo júbà rẹÌbá re o, mọ wá rí
 

Download Mp3 Here


Can't find your desired song? SEARCH HERE
REQUEST ANY SONG? CLICK HERE


Subscribe For Our Latest Blog Updates. Join 28,343 Other Subscribers>


UPLOAD YOUR SONG HERE


CLICK HERE TO COMMENT ON THIS POST

WE ARE ON SOCIAL MEDIA

Facebook | Twitter | Instagram | Youtube

Leave a comment

Enter Your Name (Optional)

Enter Comment Below


     
ABOUT US |  CONTACT US |  CONTENT REMOVAL(DMCA) | DISCLAIMER |  TERMS OF USE |  PRIVACY POLICY |  REQUEST SONG


   
Powered by PraiseZion Media
Copyright © 2023 PraiseZion.com All Rights Reserved