Yinka Ayefele – Ohun Oju Mi Ri
Posted by: Smart || Categories: Music
Download this track from Yinka Ayefele titled Ohun Oju Mi Ri. Olayinka Joel Ayefele, fondly called Yinka Ayefele, is a famous Nigerian gospel musician and entrepreneur. His name is one of the most popular names among Yoruba gospel music lovers. The veteran singer has released over 15 albums, earning him over 200 awards in Nigeria and abroad. Yinka is also the owner of Fresh FM in Ibadan. Use the link below to stream and download this track.
Lyrics of Ohun Oju Mi Ri by Yinka Ayefele
Ọmu mi lati inu Ira wa
O gbese mi lori apata
O fi orin didun si mi lenu
Orin ayo halleluyah
Ọmu mi lati inu Ira wa
O gbese mi lori apata
O fi orin didun si mi lenu
Orin ayo halleluyah
Ọmu mi lati inu Ira wa se
O gbese mi lori apata
O fi orin didun si mi lenu
Orin ayo halleluyah
Ọmu mi lati inu Ira wa
O gbese mi lori apata
O fi orin didun si mi lenu
Orin ayo halleluyah
Ohun oju mi ri, enu mi kole so
Ohun oju mi ri, enu mi kole so
Oga mi ma losi pé kerepe ran mi l’omi
Oga mi ma losi pé kerepe ran mi l’omi
Igbin aiye yi lo ye mi gere to de fo
Igbin aiye yi lo ye mi gere to de fo
Omi oju mi wa koni toro ge to ge
Omi oju mi wa koni toro ge to ge
Opo Ota mi won fara han gege bi ore
Opo ore mi wan fara hàn bi ota
Edumare dakun ma jẹ ki nisoro
Ọba òkè dakun jẹ kí n le fi oro ayé mi ma gbitan
Ilé ayé pé méjì ko mo bo ṣe rí na
Ilé ayé le koda, ẹgba gbe je ni
Ohun oju mi ri mele royin fáráyé tan
Bi n ba ni ki n ma royin a su mi
Edumare dakun jẹ kí n le f’oro ayé mi ma gbitan
Bẹ, asiko ni lamba lo mi o mọ bo le yiwo
Mo n tele awọn ti mo mọ bi aṣaju
Oga mi ma losi pé kerepe ran mi l’omi
Oga mi ma lọsí pe kerepe ran mi l’l’omi
Omi oju mi wa kun ni toro ge to ge
Igba mo sí subu tan, mo wa mo pe ayé yi fele
Eni a ba gbokan le gan ma lo tun wa ṣe ni
Ero ba mi ki mama mi ma tete walẹ
Iṣẹ Aye yi lo so omo nu bi obo
Edumare dakun jẹ kí n le f’oro ayé mi ma ṣetan
Ohun ojú mi ri, enu kólé royin laye
Ohun oju mi ri enu mi kole royin tan
Oga mi sí pé kerepe ran mi l’omi
Oga mi sí pé kerepe ran mi l’omi
Egbi ayé yi lo yemi kere to defo
Egbi ayé yi lo yemi kere to defo
Omi oju mi wa koni toro ge to ge
Edumare dakun ma jẹ ki n nisoro
Ibi ota ti ni fara hàn bi ore
Ti ọrẹ sìn fara hàn gẹgẹ bí ota
Ọba òkè dakun jẹ kí n le f’oro ayé mi ma gbitan
Mori kekere loni o awọn angẹli won duro lapa otun
Mori keke ìlérí ife rẹ, awọn angẹli won duro lapa òsi rẹ
Ahh ọlọrun ayo
Mori kekere loni o awọn angẹli won duro lapa otun
Mori keke ìlérí ife rẹ, awọn angẹli won duro lapa òsi rẹ
Ahh ọlọrun ayo
Ahh ọlọrun ayo
Ahh ọlọrun ayo
Ahh ọlọrun ayo
Ahh ọlọrun ayo
Ahh ọlọrun ayo
DOWNLOAD MP3 HERE
Can't find your desired song? SEARCH HERE
REQUEST SONG HERE
Subscribe For Our Latest Blog Updates. Join 28,343 Other Subscribers>