Welcome to PraiseZion


NEED PRAYER/COUNSELING? CLICK HERE

Shola Allyson – Ope

Posted by: || Categories: Music


Ope by Shola Allyson Mp3 Download + Lyrics

Download this track from Shola Allyson titled Ope. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.

Use this link below to stream and download the track

Lyrics Of Ope by Shola Allyson

Nipa ipa ko, kii s’agbara l’oro se ri b’o se riB’o ti wu ko ri Oluwa s’olododo f’awon to gba A gboOye aye o ye ni to sugbon o da wa loju Alaanu l’Olorun waA gbe ni leke, Oluke ni, Oluyan ni solaAseyiowu O se o Baba t’o fi wa dara iyanu (Iba Iba Iba)Iba oIba f’Olorun Eledumare to l’ogo oooo (iba)Iba Iba Iba naa ni o (Iba o)Iba Iba Iba oA juba, a juba, f’Olorun to ni gbogbo ogo, Oun ni (Iba o)Iba l’awa f’aye wa ju oo (Iba o)Iba, a juba Re, Iwo nikan lo ni gbogbo ijuba a wa (Iba o)Iba Iba IbaOpe ni fun o Edumare, Oba to layeAdani magbagbe Oba Oke to segun fun waBi ko ba se ‘Wo too seyi fun wa ki la a ba wi oOpe wa ree o, Oba to to gb’oju leA mo riri oore t’Oo se fun wa o, Oba to to gb’oju leOkeere ni mo gbe wa o, mo gburo ise OluwaTa lo dabi Re ninu aanu, adani ma gbagbe eniBi’da keji ba sele, Oo sa ma j’Olohun lo niO ka wa m’awon t’Oo pe, t’Oo yanOba to to gb’oju leO ka wa m’awon t’Oo s’aanu funA o le dupe tan lai lai lai laiYou are the Lord above all the earthKabi o o si oYou are the Lord above all the earthKabi o o si oOju mi ti ri, eti mi ti gboIyanu Re yi aye kaMo gbo ninu eri awon eniyan mimoMo ri ninu itan, emi gangan ni itanGbogbo ise Re daa da’a da’a da’a niAburu kankan o t’odo Re waOhun gbogbo lo le yi padaSugbon rara t’ododo Re koKabiyesi oooo, mo se ba ReOba to ju gbogbo oba loKabiyesi oooKabiyesi o mo se ‘ba ReOba to ju gbogbo oba loAfuye gege ti o see gbeJigbinni jigbinni bi ate ilekeKabiyesi o mo se ‘ba ReOba to ju gbogbo oba loAfuye gege ma ma see gbeJigbinni jigbinni bi ate ilekeKabiyesi o mo se ‘ba ReOba to ju gbogbo oba loMo se ‘ba Re o, mo se ‘ba ReMo f’ori bale mo gb’owo sokeMo se’ba Re o, mo se ‘ba ReNi ‘rele okan mi ni mo wariKabiyesi o mo se ‘ba ReOba to ju gbogbo oba loKabiyesi oKabiyesi o mo se ‘ba ReOba to ju gbogbo oba loAigbagbo bila temi l’OluwaOun yoo si dide fun igbala miKi n sa ma gb’aduraOun o se ‘ranwo‘Gba Krist’ wa l’odo mi ifoya ko siB’ona mi ba su, Oun lo sa n to miKi n sa gboran sa Oun o si peseB’ona mi ba su o, Oun lo sa n to miKi n sa gboran sa Oun o si peseBi ‘ranlowo edaBi ‘ranlowo eda gbogbo sakiOro t’enu Re n so yoo bori dandanHallelujahHosannaHallelujahHossanahHallelujah l’awon orun nkeHossanahAwa aye naa nke tiwa, hallelujahHossanahHallelujahHossanah (hossanah hossanah l’awa nko)Hallelujah (Hossanah)Gbogbo iseda n f’ori bale f’ooko Re, HallelujahHossanahHallelujahHossanahOur FatherWe bless YouOlutoju wa, we bless YouWe bless YouEni to l’emi to fun wa mi, we bless YouWe bless YouEni t’O fi ‘ranwo fun wa, we bless YouWe bless YouEeeh Oluwa, Eeeeh ehhh OluwaEeeeh Oluwa o b’ona ba suOluwa f’ona han wa, Oluwa oEeeh Oluwa, Eeeeh ehhh Oluwa oEeeeh Oluwa o b’ona ba suOluwa f’ona han wa, Oluwa oIfe t’O fi han ko je ki n ro peYio fi mi sile ninu wahalaOun to mu mi de bi s’olododo lati sun mi siwajuKo ni fi mi sile bo ti le wu ko ri oIranwo ti mo siIranwo ti mo si n ri lojojumoO ki mi l’aya pe emi yoo laajaOlorun agbayeYou are mightyOlorun to wa ninu awon orun to ju awon orun lo (You are mighty)Ori obiri aye lo n gbe imole lo fi saso bora o (You are mighty)O f’orun se ‘le,O f’aye s’apoti itise maa s’ola Re lo (You are mighty)You are mighty, You are wonderful,You are awesome, oruko Re niyen (You are mighty)Olorun agbaye (You are mighty)Sebi ‘Wo lo f’oju orun saso boraOlorun agbaye o, You are mighty oOlorun agbaye o You are mightySebi ‘Wo lo f’oju orun saso boraOlorun agbaye o, You are mighty oOruko Oluwa ile iso agbara niOlododo sa wo’nu re, o ri iyeEmi naa, mo sa wo’nu re, mo ri iyeOruko Re ti niyin to (Oluwa Oluwa)Oluwa, Oluwa wa, oruko Re ti niyin toOluwa Oluwa OluwaOluwa, Oluwa wa, oruko Re ti niyin toAlagbara l’Olorun waAgbara agbara agbara yi po o, agbaraOba to ba riru omi okun wi, agbara Re poAgbara agbara agbara yi po o, agbaraA wo ‘gba aarun, ma gb’eje l’ooko ReAgbara agbara agbara yi po o, agbaraOba to f’aanu tan ‘mole s’ona awon to gb’oju s’oke siAgbara agbara agbara yi po o, agbaraO f’agbara gba ni lowo alagbara gbangba ti n f’owo agbara je ni niyaAgbara agbara agbara yi po o, agbaraGbogbo iseda n wariri ni’waju agbara ReAgbara agbara agbara yi po o, agbaraIba oIba f’Olorun Eledumare to ni gbogbo ogo (Iba)Iba Iba a (Iba)A juba, a juba, gbogbo ijuba wa tire ni (Iba)Olorun to ni gbogbo ogo, iba f’ooko Re (Iba)Gbogbo iseda n f’ori bale ni’waju Re (Iba)Iba Iba Iba aIse Re po, o po, o po, o po gaan ni (Iba)Awon ise iyanu t’Oo ti se, ta lo le ka won tan? (Iba)Ta lo le so ewa Re to po, to po gaan ni? (Iba)Iba Iba Iba Iba (Iba)Gbogbo eemi mi, gbogbo wiwa mi, tire lo je, mo juba (Iba)Titi aye ni ma ma se’ba Re lojojumo (Iba)Maa sin O d’opin igba mi, Iba Iba (Iba)Iba aaa

Download Mp3 Here


Can't find your desired song? SEARCH HERE
REQUEST ANY SONG? CLICK HERE


Subscribe For Our Latest Blog Updates. Join 28,343 Other Subscribers>


UPLOAD YOUR SONG HERE


CLICK HERE TO COMMENT ON THIS POST

WE ARE ON SOCIAL MEDIA

Facebook | Twitter | Instagram | Youtube

Leave a comment

Enter Your Name (Optional)

    Â

Enter Comment Below


     
ABOUT US |  CONTACT US |  CONTENT REMOVAL(DMCA) | DISCLAIMER |  TERMS OF USE |  PRIVACY POLICY |  REQUEST SONG


   
Powered by PraiseZion Media
Copyright © 2024 PraiseZion.com All Rights Reserved
Â