Welcome to PraiseZion


NEED PRAYER/COUNSELING? CLICK HERE

Shola Allyson – Adura Ololufe

Posted by: || Categories: Music


Adura Ololufe by Shola Allyson Mp3 Download + (Lyrics)

Download this track from Shola Allyson titled Adura Ololufe. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.

Use this link below to stream and download the track

Lyrics Of Adura Ololufe by Shola Allyson

Adura mogba fun e ololufe miIre ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore miOo ni kagbako l’aye oo ni r’ogun akobaOo ni s’irin l’aye be oo ni t’oju ile moleAinif’okanbale o ni y’odo re lailailailailaiOo ni m’osi l’aye, aye re a ma dara siIfe eledumare ree e ooo ore miO fewa fun re, o fewa f’ayo taa ba barawa s’otitoAngeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s’iseIranse alaanu re wa pelu t’emi nwon njo rin po ni
Ibaase ‘wo layo pupo latagbala eledumare wa inu oluwa aa dun siIbaase’ wo layo pupo latagbalaEledumare wa o, inu oluwa aa dun si wa
Oba ni a lowo a bi’moOba ni a s’owo a j’ereOba ni a r’aje jeunImole aa ma tan si
Imoran mi ree fun e ooo oloro miImoran ni mo n gba e ninu ife to jin oloro mi maa gboPe ko maa s’ora se, ore mi at’orun s’ora seJowo f’arabale ko gb’emi olorun l’aye koM’okan at’eti re kuro ninu etan to kun’nu ayeGbogbo ohun to ma n dan ko ni wura,Joo ma fi ididi w’ola, ola aa to ni wa,Fitila ona re o ni ku lailai, aye re a ma dara si.
Owo o ni wan n’ile waOwo Olorun nbe lara waOwo Oluwa nba wa loImole a ma tan si
Ope ti mo nda l’ojojumo ree ore okan t’eledua fun mi maa gboModupe mo yin’le f’olu to gbe mi pade alaanuMosope mi o kuta l’oju oja ife, eleda lo ba mi seAlabarin t’eledua yan fun o gangan ni mojeAlabase t’olorun fifun mi gangan ni iwo jeAjose wa a maa mayo wa o nfun wa l’ayo,Ka sa maa sora se Ajose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora se
Oba ni a lowo a bi’moOba ni a s’owo a j’ereOba ni a r’aje jeunImole aa ma tan si
Ife okan mi ree, ore okan mi tipetipe maa gboPe ka je imole, imole wa ko tan f’araye riKa f’ara wa lowo, ka jo rin f’olu, ka nipa rere f’ayoEni waye lai mu’fe orun se, asan bansaAa r’owo lo, aa f’ola we, ka s’ise taa ran wa wa pa bi funAjose wa a maa mayo wa o nfun wa l’ayo, ka sa maa sora seAjose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora se.
Ajose wa a maa mayo wa…
Ka sa maa sora se…
 

Download Mp3 Here

 


Can't find your desired song? SEARCH HERE
REQUEST ANY SONG? CLICK HERE


Subscribe For Our Latest Blog Updates. Join 28,343 Other Subscribers>


UPLOAD YOUR SONG HERE


CLICK HERE TO COMMENT ON THIS POST

WE ARE ON SOCIAL MEDIA

Facebook | Twitter | Instagram | Youtube

Leave a comment

Enter Your Name (Optional)

Enter Comment Below


     
ABOUT US |  CONTACT US |  CONTENT REMOVAL(DMCA) | DISCLAIMER |  TERMS OF USE |  PRIVACY POLICY |  REQUEST SONG


   
Powered by PraiseZion Media
Copyright © 2024 PraiseZion.com All Rights Reserved