Welcome to PraiseZion


NEED PRAYER/COUNSELING? CLICK HERE

JayMikee – Talebale +[Video & Lyrics]

Posted by: || Categories: Music


Talebale by JayMikee Mp3 Download

Download Nigerian gospel song from JayMikee titled Talebale. Popularly known as Jaymikee, Joshua Mike Bamiloye is the second son of Evangelist Mike and Gloria Bamiloye, drama evangelists, ministers and veteran actors of the Mount Zion Faith Ministries. Born on November 7, 1997, Joshua Mike Bamiloye has grown to become a music artiste, movie actor and evangelist.

Use this link below to stream and download track. 

WATCH VIDEO

Lyrics Of Talebale by JayMikee

A jẹ’ bí ọmọdé tí ìyá rẹ rán lọ s’ọjàAh ah ah ah ah ahỌjà ilé ayé láti ra láti táAh ah ah ah ah ahṢùgbọ’n tí ilẹ’ bá bẹ’rẹ’ si ní ń ṣúTí òkùnkùn bá bo ‘lẹ’Ti oníkálukú bá pá lẹ ọjà mọMa jẹ’ kí ń gbàgbé láti kọ ‘ri si ‘lè

Jésù ó jọ’wọ’ ó má má jẹ’ ń kùnàKíi má bá ṣ’ ègbé ló ṣe kú fún miJésù ó jọ’wọ’ ó má má jẹ’ n ṣìnàKíi má bá ṣ’ ègbé ló ṣe kú fún miNígbà t’álẹ’ bá lẹ’T’ọjà ayé túJẹ’ kí n r’ ọkọ rẹ bá reléNígbà t’álẹ’ bá lẹ’T’ọjà ayé túJẹ’ kí n r’ ọkọ rẹ bá relé

Ìjọba ọrùn dá bí àwọn wúńdíá mẹ’wàáAh ah ah ah ah ah ahTí wọn mú fìtílà wọn lọ pàdé ọkọ ìyàwóAh ah ah ah ah ah ahElédùmarè má má jẹ’ kí n dí alaigbagbọnFún mi ní ọgbọ’n bí àwọn wúńdíá ọlọ’gbọ’nKólóbó mì rèé óRọ’ kún pẹ’lú òróró rẹKíi n fí dúró dé ọ’

Jésù ó jọ’wọ’ ó má má jẹ’ ń kùnàKíi má bá ṣ’ ègbé ló ṣe kú fún miJésù ó jọ’wọ’ ó má má jẹ’ n ṣìnàKíi má bá ṣ’ ègbé ló ṣe kú fún miNígbà t’álẹ’ bá lẹ’T’ọjà ayé túJẹ’ kí n r’ ọkọ rẹ bá reléNígbà t’álẹ’ bá lẹ’T’ọjà ayé túJẹ’ kí n r’ ọkọ rẹ bá relé

Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi délé (Bá relé)Mú Mí délé ó ó Mú mi déléMú Mí délé ó ó Mú mi déléMú Mí délé ó ó Mú mi déléMú Mí délé ó ó Mú mi délé

Jésù ó jọ’wọ’ ó má má jẹ’ ń kùnàKíi má bá ṣ’ ègbé ló ṣe kú fún miBàbá jọ’wọ’ ó má má jẹ’ n ṣìnàKíi má bá ṣ’ ègbé ló ṣe kú fún miNígbà t’álẹ’ bá lẹ’T’ọjà ayé túJẹ’ kí n r’ ọkọ rẹ bá reléNígbà t’álẹ’ bá lẹ’T’ọjà ayé túJẹ’ kí n r’ ọkọ rẹ bá reléBaba Ah!

Download Mp3 Here


Can't find your desired song? SEARCH HERE
REQUEST ANY SONG? CLICK HERE


Subscribe For Our Latest Blog Updates. Join 28,343 Other Subscribers>


UPLOAD YOUR SONG HERE


CLICK HERE TO COMMENT ON THIS POST

WE ARE ON SOCIAL MEDIA

Facebook | Twitter | Instagram | Youtube

Leave a comment

Enter Your Name (Optional)

Enter Comment Below


     
ABOUT US |  CONTACT US |  CONTENT REMOVAL(DMCA) | DISCLAIMER |  TERMS OF USE |  PRIVACY POLICY |  REQUEST SONG


   
Powered by PraiseZion Media
Copyright © 2024 PraiseZion.com All Rights Reserved