Pastor Adelakun Ayewa – Live Concert
Get this track from Pastor Adelakun Ayewa which he titled Live Concert. Pastor Adelakun Ayewa is a Nigerian gospel singer, songwriter and televangelist. Use this link below to stream and download Live Concert by Pastor Adelakun Ayewa
WATCH VIDEO
Lyrics
Amona o
Amona tete wa o, amona tete bo
Amona tete wa o, amona tete bo (Tori pe)
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
Amona tete wa o, amona tete bo
Amona tete wa o, amona tete bo (Tori pe)
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
Jesu Kiristi l’amona
Oun lo le tun le aye wa se
A n reti re o Baba, a fe r’oju re
Igba ti Jesu ba de, l’aye yi to le toro o
Igba ti Jesu ba de, l’aye yi to le dara
Ikiri lojojumo, nise lofin gori ofin
Sibe sibe ara mi gbogbo, aye o fi be toro
Ologun n be lode, aye n rojo kiri
Oselu tun tun wo be o, igbe laraye nke
Oselu to koja lo, ejo laye n ro
Ologun lo tun wobe o, Igbe laraye n ke
Otito o nile mo, iro laraye n fe
Ododo o ri bi gba o, ese ti bori aye
Afi ti Jesu ba de, laye yi to le toro
Afi ti Jesu ba de, laye yii to le dara
Amona tete ma bo o, amona tete ma bo wa
Aye n daru lo o, ese n gori ese lojojumo
Aye ma dobiripo, amona tete

Amona tete wa o, amona tete bo (amona o)
Amona tete wa o, amona tete bo (nitori pe)
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
Amona tete wa o, amona tete bo (nitori pe)
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
Amona o
Amona tete wa o, amona tete bo (amona o)
Amona tete wa o, amona tete bo (nitori pe)
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
Amona tete wa o, amona tete bo (nitori pe)
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
Ara e je a ranti, Igba aye Noah o
Ema je a gbagbe gbogbo wa o, iku omi to koja o
Olowo aye n wi, won niro ni Noah n pa
Talika so ti re o, won nibo l’ojo ti n bo wa
Lalaijiyan rara, nise ni Noah tesiwaju
Lalaibikita o, omo olorun o we yin wo o
Pelu iranlowo Oluwa, Oko Noah pari
Eranko n wole, era n wonu oko o
Awon eye oju orun gbogbo, gbogbo won lo sare wole
B’elede se y’obun to, sibe o raye wole
Ibe la r’omo eniyan o, to n je ti won n mu
B’ewure ti j’alai gboran to, kia lo sare wole
Nibe la r’omo eniyan o, to n so pe’ro ni
Won komo jade, won se’gbeyawo kiri
Won o beru ofin Oluwa wa Oba wa, gbogbo won lo n j’aye
Bo ti ri nigbaye Noah, o un be nisi yi o
Bo ti ri nigbaye Noah, o un be nisi yi o
Opo lo ti n so, wipe Jesu o nide mo o
Amona tete ma bo o, amona tete ma bo wa
Aye n baje o, ese n gori ese lojojumo
Aye ma dobiripo, amona tete
Ema je a gbagbe gbogbo wa o, iku omi to koja o
Olowo aye n wi, won niro ni Noah n pa
Talika so ti re o, won nibo l’ojo ti n bo wa
Lalaijiyan rara, nise ni Noah tesiwaju
Lalaibikita o, omo olorun o we yin wo o
Pelu iranlowo Oluwa, Oko Noah pari
Eranko n wole, era n wonu oko o
Awon eye oju orun gbogbo, gbogbo won lo sare wole
B’elede se y’obun to, sibe o raye wole
Ibe la r’omo eniyan o, to n je ti won n mu
B’ewure ti j’alai gboran to, kia lo sare wole
Nibe la r’omo eniyan o, to n so pe’ro ni
Won komo jade, won se’gbeyawo kiri
Won o beru ofin Oluwa wa Oba wa, gbogbo won lo n j’aye
Bo ti ri nigbaye Noah, o un be nisi yi o
Bo ti ri nigbaye Noah, o un be nisi yi o
Opo lo ti n so, wipe Jesu o nide mo o
Amona tete ma bo o, amona tete ma bo wa
Aye n baje o, ese n gori ese lojojumo
Aye ma dobiripo, amona tete
Amona o
Amona tete wa o, amona tete bo (amona o)
Amona tete wa o, amona tete bo
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
Amona tete wa o, amona tete bo
Aye n ba je o, amona tete bo
Aye n daru o, amona tete bo
A n reti e Baba
Eranko gbogbo wole tan, ateye oju orun
Noah pelu idile re o, won n ko jije mimu
Nigba tise pari tan, Noah ba wonu oko o
O wonu oko lo tarara, pelu eniyan meje
Eniyan meje oun, idile Noah ni gbogbo won
Nigba ti won wole tan, Oba ogo t’ilekun o
O ku awon alaigboran o, lati gba’dajo won
Bo ti ri nigbaye noah, oun be nisi yi o
Bo ti ri nigbaye noah, oun be nisi yi o
Opo lo ti n so, wipe Jesu o ni de mo o
Araye n pa ro, wo ni kosi Baba
Baraye ba wi titi, won a so pe kosi Jesu
Won ni ko s’olugbala kankan, won l’aye o ni pare
Won loun ta ba je laye, oun la o mu lo s’orun
Opo lo tile ni ko s’orun, won ni ta ba ku o pari o

Ko wa sile aye o, amona tete ma bo
Ko wa t’aye se o, amona tete ma bo
Ki won le gbagbo, pe wo nikan lolugbala o
Ka ye le gbagbo, pe wo l’oba to n gbani
Amona tete ma bo o, amona tete ma bo wa
Aye n daru o, ese n gori ese lojojumo