Shola Allyson – Olorun Awon’Mo Ogun
Olorun Awon’Mo Ogun by Shola Allyson Mp3 Download + Lyrics
Download this track from Shola Allyson titled Olorun Awon’Mo Ogun. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Olorun Awon’Mo Ogun by Shola Allyson
Ògo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn Ọlọ́run àwọn ọmọ ogúnÒgo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ọlọ́run àwọn ọmọ ogúnỌba tó f’amo mo wá
Ọba tó lẹ’ mi wá Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ọlọ́run àwọn ọmọ ogunỌba t’ó f’amo mo wá
Ọba t’ó lẹ’ mi wá o Ọlọ’run àwọn ọmọ ogún Ọlọ’run àwọn ọmọ ogúnNíbi tó lẹ’wá julo ni Ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o Imọ’lẹ’ láṣọ re Ọlá lo fi ṣá’so boraNíbi tó lẹ’ wá julo ni ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé ni’wo wá o Imọ’lẹ’ láṣọ rẹ O ó Ọlá lo fi ṣá sọ boraMo padà wá bí orísun ìfẹ’ àkókò
Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi o Ọba tó lẹ’ mi mi Ọba tó ní gbà miMo padà wá bí orísun ìfẹ’ akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o Ọba tó lẹ’ mi mi Ọba tó ní gbà miAhhhhh Ahhhhh
Ìwọ lọ lèmi mi ò Ìwọ lo nígbà miÌṣẹ’lẹ’ inú ìṣẹ̀dá nṣá’fihàn àgbàrá rẹ
Àwọn ohùn tàri n ṣáfihan ìṣe rẹ o Pẹ’lú ifilelẹ’ tí ó lè Páráda láì láì Àrà ọwọ Rẹ ni gbogbo wọ́nṢe bí èyí tà ri là ń wi
Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye Àìmọye làwọn tá kan n mo l’àrà Ẹ’dá ó lè ṣá kàwé wọnIbí tó lẹ’wá julo ni ìwọ gbé
órí obiiri ayé ni’wo wá o Imọ’lẹ’ láṣọ rẹ O ó Ọlá lo fi ṣá sọ boraMo padà wá bí orísun ìfẹ’ àkókò
Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi Ọba tó lẹ’ mi mi Ọba tó ní gbà miMo padà wá bí orísun ìfẹ’ akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh Ọba tó lẹ’mi mi Ọba tó ní gbà miÒgo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn Ọlọ́run àwọn ọmọ ogúnÒgo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Call: Ọba tó fún mí lé mi ọba tó lémi mi ẹni tó lé mi gàn gàn Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Call: Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tà le fara gbà mú là ń jẹ anfani ẹ Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun Call: Àìmọye àwọn èyí tá’ ó lé mọ’ bíi kò ṣé gbà ta ba sunmọ ibùgbé rẹ Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Call: Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ’n bá ti ọgbọ’n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún Resp: Ọlọ’run àwọn ọmọ ogún Call: Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ Resp: Ọlọ’run àwọn ọmọ ogún Call: ẹni n bẹ lórí ìtẹ’ á sì wà síbè sì bí ó ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kànkan ó sì Resp: Ọlọ’run àwọn ọmọ ogun Call: Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo agbara gbogbo ìjọba tìrẹ ṣá ní Reap: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún