Lanre Teriba – Olódùmarè
Olódùmarè by Lanre Teriba Mp3 Download
Download this track from Lanre Teriba titled Olódùmarè. Olanrewaju Michael Afolabi Teriba popularly known as Arotise is a Nigerian gospel musician, singer, songwriter and minister. He came to the limelight after the release of his debut album Atorise in 2000. Lanre Teriba was born on May 13 in Ogun State to Pa late Samuel Oladimeji Awomosu Teriba (father) and late Prophetess Mrs Hannah Atinuke Teriba
Use the link below to stream and download the song
Lyrics Of Olódùmarè by Lanre Teriba
This is Lanre Teriba (Atorise)
Oro to wá ní le yí Oro to wá ní le yí Owo lọ ma solve ẹ Advice kò ooo E ma f’ejò pá miNo tension
E yẹ ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l’owo lowo No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l’owo lowo, Mi ó kánjú waiye Mi ó ní konju lọ No long thing ashi ma bá wọn lowo K’ anybody ye ma pressure mi T’oba nlowo ashi ma báwọn l’owo lowoOlódùmarè
Olodumare wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò’kan to o wọn’ba mi ninuje Olódùmarè Olodumare wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò’kan to o wọn’ba mi ninujeAs I no dey here for competition
If you say you pass me no problem Me too I pass somebody B’opé b’oyá o ni ile aiye congratulation akárí gbogbo waOlódùmarè
Olódùmarè wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò’kan to o wọn’ba mi ninujeNo tensionanybody ye ma pressure mi T’oba nlowo ashi ma báwọn lowo l’owo
E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l’owo lowo No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l’owo lowo Mi ó kánjú waiye Mi ó ní konju lọ No long thing ashi ma bá wọn lowo l’owo K’Olódùmarè
Olódùmarè wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò’kan to o wọn’ba mi ninuje Olódùmarè Olódùmarè wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò’kan to o wọn’ba mi ninujeIya mi ó lowo de bipe wa pin owo kan mi lojo kan
Baba mi o ni ile de bipe wa pin ile kan mi t’obaya Iyen lo mu mi san sokoto ti mo fi gbogo igba hustle K’awon omo ti mo bi ma ba ji ya ti mo je Iyen to mu mi san sokoto ti mo fi gbogo igba hustle K’awon omo ti mo bi ma ba ji ya ti mo jeNo Tension ooo
No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l’owo lowo No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l’owo lowo Mi ó kánjú waiye Mi ó ní konju lọ No long thing ashi ma bá wọn lowo Kí anybody ye ma pressure mi T’oba nlowo ashi ma báwọn l’owo lowo