Tope Alabi – Kabiyesi
Kabiyesi by Tope Alabi Mp3 Download
Download this track by Tope Alabi titled Kabiyesi. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She hails from Yewa in Ogun State. Alabi developed an interest in music at a young age, participating in her church choir and singing during school events.
Use the link below to stream and download the song.
Lyrics of Kabiyesi by Tope Alabi
Ká bí o si o, mo júbà rẹ
Oṣù bá rẹ, gbọmọ-gbọmọ lo ń ro Mo ki o ti’lu, ti dídún o, Ọba tọ ní mí Ìbá rẹ o, Ọba áńgẹ’lì (Ọba to lòun gbogbo, tòun ṣẹ òun gbobo)Kabiyesi oo, mo júbà rẹ (ehn, ehn, ehn)
Àdá ní pe (adá ní pe), à dá ní dá Àpá ńlá tó so aiye’ ro o, mo júbà rẹ (mo júbà rẹ o) Ìbá re o, mo wá ríGbogbo ipá, gbogbo àgbàrá
Ọrọ godo ganya, àṣírí ọrun pẹlu aiye’ Ko mámá s’àfi we rẹ o, ibà o (ko s’àfi we rẹ o, ibà o) Ọrọ ńlá to f’ọrọ dà ayé ọrun Èémí inú rẹ lo mí samo, to d’ènìyàn Aṣẹ̀dá Ọba ‘lú ọrùn o, tótó (tótó ọlá rẹ, ibà)Kabiyesi o, mo júbà rẹ (ipá ńlá to borí gbogbo ipa, ehn-ehn)
Àdá ní pe (adá ní pe), à dá ní dá (à dá ní dá o) Àpá ńlá to so aiye’ ro o, mo júbà rẹ (mo júbà rẹ o) Ìbá rẹ o, mo wá ríMo rí bá, mo ri ibà, Ọba ọrun
Akọda, Aṣẹ̀dá, àdììtú ní o O dà ‘yé dà, ó dà òun gbogbo Àláṣẹ lórí ikú àti abeti lukara Ìwọ lọrọ ìkòkò, ní gbangba lo wá o Ayé a kọjá, ọrun a kọjá lọ Ìtẹ’ rẹ lọrun kíiṣí, ní gbo ta o le rọ l’óye Arọ méta tí o d’ọbẹ’ nu, tọ dúró wá mú (o dúró wá mu)Kabiyesi oo (wámú-wamu), mo júbà rẹ (ah)
Àdá ní pe, à dá ní dá (òkè tógá ti o le ja bọ láì-láì) Àpá ńlá tó so aiye’ ro o, mo júbà rẹ (ipa ńlá to so ilé ayé ro) Ìbá re o, (mo wá rí o) mo wá ríKabiyesi oo (Bàbá, Bàbá) mo júbà rẹ
Àdá ní pe (alágbára gíga), à dá ní dá (ahh) Àpá ńlá tó so aiye’ ro o, mo júbà rẹ Ìbá re o, mọ wá rí