Welcome to PraiseZion



HOME |   |  SERMONS
|  JOBS |  INSTRUMENTAL | MIXTAPES |  DEVOTIONAL

SEARCH CONTENTS (Use Name Or Title)


Tope Alabi – Afoju {Lyrics}

Tope Alabi – Afoju

Tope Alabi – Afoju Mp3 Download

Tope Alabi famous Nigeria gospel singer, has come up with a masterpiece tagged “Afoju” the song is captivating and mind-blowing. The sound is amazing.

Lyrics Tope Alabi – Afoju 

To ba n rin l’okunkun

Ko le mo, afoju ni

To ba n jeun eleera

Ko le mo, afoju ni

To ba r’omoge to rewa eeeh

Ko le mo rara

Okunkun o da ma so mi s’okun osan Eledua

To ba n rin l’okunkun

To ba n rin l’okunkun ko le mo rara

Ko le mo, afoju ni afoju ni

To ba n jeun eleera eh

Ko le mo, afoju ni afoju ni bawo lo se fe mo

To ba r’omoge to rewa eh ah

Ko le mo rara agaga eeh

Okunkun o da ma so mi s’okun osan Eledua

Oju L’obara o, okunkun o da

Eda mi gbo

Etewo adura araye, ka ma f’opa rin Amin o

Eniyan buru ninu aye won le pokun meko fun ni beeni aye buru

Aye mi d’owo re, ba mi so, mo mi n bebe o aye mi d’owo re o

To ba n rin l’okunkun ma je k’omo araye so mi

Ko le mo, afoju ni s’okunkun e

To ba n jeun eleera

Ko le mo, afoju ni

To ba r’omoge to rewaa eeeh

Ko le mo rara ko le mo rara

Okunkun o da ma so mi s’okun osan Eledua ma so mi s’okunkun osan o

Gbogbo abarapa, e ranti abirun e ma ranti won

E ma se’ranlowo, ema di kun won l’eru rara

Ti won to won gbe, oro aye kanpa o

Ara aye e buru

To ba fe ni loju, won a tun f’ata s’enu Aye

To ba n rin l’okunkun

Ko le mo, afoju ni

Bawo lo se femo

To ba n jeun eleera

Ko le mo, afoju ni At’owuro, at’osan, at’ale

To ba r’omoge to rewa eh lo dudu l’oju afoju

Ko le mo rara ko le mo o

Okunkun o da ma so mi s’okun osan Eledua Ma so mi s’okun ooh

Oju L’obara o, okunkun o da

Eda mi gbo eda mi gbo

Etewo adura araye, ka ma f’opa rin unh unh

Eniyan buru ninu aye won le pokun meko fun ni eh

Aye mi d’owo re, ba mi so, mo mi n bebe o ba mi so o Baba

To ba n rin l’okunkun To ba rin l’okunkun

Ko le mo, afoju ni Bawo lo se femo

To ba n jeun eleera To ba n jeun

Ko le mo, afoju ni To ba n jeun alayan

To ba r’omoge to rewa eh eeeh

Ko le mo rara ko le mo rara

Okunkun o da ma so mi s’okun osan Eledua Ma so wa s’okun ooh

To ba n rin l’okunkun ah ah ah ah

Ko le mo, afoju ni Gbogbo abarapa

To ba n jeun eleera

Ko le mo, afoju ni E toju afoju yin

To ba r’omoge to rewa eh Mo nigbagbo pe

Ko le mo rara lojo ojo kan

Okunkun o da ma so mi s’okun osan Eledua won a l’aju bi ti…

DOWNLOAD MP3

Listen and share your thoughts below

| Categories: Music

CLICK HERE TO COMMENT ON THIS POST

WE ARE ON SOCIAL MEDIA

Facebook | Twitter | Instagram | Youtube

0 Comments

LEAVE A COMMENT

Type Name Below

Type Comment Below

« | »