Ajulo Jesus – Obe Ti’n Sore Fun Ni Lai Wobe
Obe Ti’n Sore Fun Ni Lai Wobe by Ajulo Jesus Mp3 Download
Download this track from Ajulo Jesus titled Obe Ti’n Sore Fun Ni Lai Wobe.
Use the link below to stream and download the song
Lyrics Of Obe Ti’n Sore Fun Ni Lai Wobe by Ajulo Jesus
Call: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba, Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi, Mo Gbo osoba fun o kare, (2x)Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o), Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi, Mo gbo osoba fun o kare, (2x)Emi dupe ore pe apa aye o kami,
Emi dupe ore pe o dami si, Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi, Mo de gbo osoba fun o kare, (2x)Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,Mo gbo osoba fun o kare, (2x)
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o), Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,Ye, Oni duro gbogbo wa,
Alanu eda Oloore mi to gbo jije mimu, Iwo la shore fun ma si re gun o, Mo gbo osoba fun o kare, (2x)Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o), Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi, Mo gbo osoba fun o kare, (2x)Call: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba, Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi, Mo Gbo osoba fun o kare, (2x)Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o), Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi, Mo gbo osoba fun o kare, (6x)