Yinka Ayefele – Ohun Oju Mi Ri
Download this track from Yinka Ayefele titled Ohun Oju Mi Ri. Olayinka Joel Ayefele, fondly called Yinka Ayefele, is a famous Nigerian gospel musician and entrepreneur. His name is one of the most popular names among Yoruba gospel music lovers. The veteran singer has released over 15 albums, earning him over 200 awards in Nigeria and abroad. Yinka is also the owner of Fresh FM in Ibadan. Use the link below to stream and download this track.
Lyrics of Ohun Oju Mi Ri by Yinka Ayefele
Ọmu mi lati inu Ira wa
O gbese mi lori apata O fi orin didun si mi lenu Orin ayo halleluyah Ọmu mi lati inu Ira wa O gbese mi lori apata O fi orin didun si mi lenu Orin ayo halleluyahỌmu mi lati inu Ira wa se
O gbese mi lori apata O fi orin didun si mi lenu Orin ayo halleluyah Ọmu mi lati inu Ira wa O gbese mi lori apata O fi orin didun si mi lenu Orin ayo halleluyahOhun oju mi ri, enu mi kole so
Ohun oju mi ri, enu mi kole so Oga mi ma losi pé kerepe ran mi l’omi Oga mi ma losi pé kerepe ran mi l’omi Igbin aiye yi lo ye mi gere to de fo Igbin aiye yi lo ye mi gere to de fo Omi oju mi wa koni toro ge to ge Omi oju mi wa koni toro ge to geOpo Ota mi won fara han gege bi oreEdumare dakun ma jẹ ki nisoro Ọba òkè dakun jẹ kí n le fi oro ayé mi ma gbitan
Opo ore mi wan fara hàn bi otaIlé ayé pé méjì ko mo bo ṣe rí na
Ilé ayé le koda, ẹgba gbe je ni Ohun oju mi ri mele royin fáráyé tan Bi n ba ni ki n ma royin a su mi Edumare dakun jẹ kí n le f’oro ayé mi ma gbitan Bẹ, asiko ni lamba lo mi o mọ bo le yiwo Mo n tele awọn ti mo mọ bi aṣaju Oga mi ma losi pé kerepe ran mi l’omi Oga mi ma lọsí pe kerepe ran mi l’l’omiOmi oju mi wa kun ni toro ge to ge
Igba mo sí subu tan, mo wa mo pe ayé yi fele Eni a ba gbokan le gan ma lo tun wa ṣe ni Ero ba mi ki mama mi ma tete walẹ Iṣẹ Aye yi lo so omo nu bi obo Edumare dakun jẹ kí n le f’oro ayé mi ma ṣetan Ohun ojú mi ri, enu kólé royin laye Ohun oju mi ri enu mi kole royin tan Oga mi sí pé kerepe ran mi l’omi Oga mi sí pé kerepe ran mi l’omi Egbi ayé yi lo yemi kere to defo Egbi ayé yi lo yemi kere to defo Omi oju mi wa koni toro ge to ge Edumare dakun ma jẹ ki n nisoro Ibi ota ti ni fara hàn bi ore Ti ọrẹ sìn fara hàn gẹgẹ bí ota Ọba òkè dakun jẹ kí n le f’oro ayé mi ma gbitan Mori kekere loni o awọn angẹli won duro lapa otun Mori keke ìlérí ife rẹ, awọn angẹli won duro lapa òsi rẹ Ahh ọlọrun ayo Mori kekere loni o awọn angẹli won duro lapa otun Mori keke ìlérí ife rẹ, awọn angẹli won duro lapa òsi rẹ Ahh ọlọrun ayo Ahh ọlọrun ayo Ahh ọlọrun ayo Ahh ọlọrun ayo Ahh ọlọrun ayo Ahh ọlọrun ayo