Shola Allyson – Imisi
Imisi by Shola Allyson Mp3 Download + Lyrics
Download this track from Shola Allyson titled Imisi. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Imisi by Shola Allyson
Imole ko tan s’okunkun
Idari ko wa lona Epo ko wa l’atupa Lai ni tan Emi mimo, mo beere (Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n’irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tanImole ko tan s’okunkun
(Imole ko tan roro lati agbala, imole) Idari ko wa lona (Epo ko wa), wpo ko wa l’atupa (Ti o ni tan, ti o ni tan), lai ni tan Emi mimo, mo beere (Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n’irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tanTi o ni tan, ti o ni tan
Ti o ni tan, ti o ni tan Imole ko tan s’okunkun (Itansan imole to mole roro) Idari ko wa lona Epo ko wa l’atupa lai ni tan Emi mimo, mo beere (Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n’irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tanOba imisi, Oba imole
Oba Aanu, Oba Ogo Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Lati odo reOba imisi, Oba imole
Oba Aanu, Oba Ogo (Aanu to mu mi de bi koni ju mi le) Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Ti o ni tanTi o ni tan, ti o ni tan (koni tan lati agbala)
Ti o ni tan, ti o ni tan Imole ko tan s’okunkun (Idari ko wa), odari ko wa lona Epo ko wa l’atupa (atupa imo mi o ni ku lai-lai) Lai ni tan Emi mimo, mo beere Waa—, wa gbe mi wo n’irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tanOba imisi, Oba imole
Oba Aanu, Oba Ogo Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Lati odo reOba imisi, Oba imole (imisi lati agbala imisi)
Oba Aanu, Oba Ogo Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Lati odo reOba imole
(Itasan Imole to mole roro) Oba Aanu, Oba Ogo (aanu to mu mi debi o ni ju mi le) Orisun imisi (ibe ni mo gboju soke si), Isewa imole Je ki imisi ba le mi Ti o ni tanTi o ni tan, ti o ni tan
(Ko ni tan lailai, ati agbala imisi n’imisi ti n wa) Ti o ni tan, ti o ni tan Imole ko tan s’okunkun (Idari ko wa lona mi) Idari ko wa lona (Epo ko wa l’atupa o) Epo ko wa l’atupa lai ni tan Emi mimo, mo beere Waa—, wa gbe mi wo n’irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tanImisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Okun o gberi, osa o gberi o, ise Baba oni imisi ni won Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Itansan imole yen ko ma tan fun mi ni irinajo mi Lati odo Oba oni imisi, lati agbala imisiImisi ko wa fun mi ti o ni tan
Imisi ko wa fun mi, ta fi irisi omo Baba imole han nigbagbogbo Imisi ko wa fun mi ti o ni tanImisi ta ko mi ni isesi imole ni gbogbo irinajo mi, lona mi
Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ta fi irisi omo baba oni imisi han, ko wa fun mi nigbagbogbo Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ko wa fun mi ti o ni tan