Shola Allyson – Ilekun Si
Ilekun Si by Shola Allyson Mp3 Download + Lyrics
Download this track from Shola Allyson titled Ilekun Si. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Ilekun Si by Shola Allyson
Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si! E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si! E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka o! Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka! Eyin to wa n’ibi imole, tan imole, imole yo! Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka! Eyin to wa n’ibi imole, tan imole, imole yo! Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!Ki lo n fa igbekun? Okun ja!
A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja! Ki lo n fa igbekun? Okun ja! A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja! Ki lo n fa igbekun? Okun ja!Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si! E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!Oba Ogo wo ‘le yi wa! (Oba Ogo wo ‘le yi wa aaaaaaaa)
Imole wo ‘le! (Imole wo ‘le eeeeeeeee) Okunkun ka! (Okunkun kaaaaaaa) Okun ja! (Okun jaaaaaaaa)Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si! E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si! E gb’ ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si! Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Eyin to wa n’ibi imole, tan imole, imole yo! Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka! Eyin to wa n’ibi imole, tan imole, imole yo! Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka! Ki lo n fa igbekun? Okun ja! A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja! Ki lo n fa igbekun? Okun ja! A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja! Ki lo n fa igbekun? Okun ja!