Shola Allyson – Ero Oja (Im’oore)
Ero Oja (Im’oore) by Shola Allyson Mp3 Download + (Video & Lyrics)
Download this track from Shola Allyson titled Ero Oja (Im’oore). Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Ero Oja (Im’oore) by Shola Allyson
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo Ero oja olomo Ja lo lo, ja lo lo Ero oja olowo Ja lo lo, ja lo lo Ero oja olomo Ja lo lo, ja lo lo Ki le ti s’oja yi si o? Ja lo lo ja lo lo Ki le ti s’aye si? Ja lo lo ja lo lo Ki le ti s’oja yi naa? Ja lo lo ja lo loE ma ma je k’oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo A bebe, e ma ma je k’oja yi tu mo wa lori Ja lo lo ja lo lo E w’oja yi se, e ba wa se k’o da Ja lo lo ja lo lo E w’oja yi se, e ba wa se k’o da Ja lo lo ja lo loA ki yin ooo, eyin agba
E ku agba eyin agba to t’agba to t’aye se, agba yin a dale Omode ni mi oooo, k’Oluwa da mi lagba Agba to n mu’le ro To to se bi imoran, mi o to gba yin ni ‘moran Ise Olorun ni mo n je Ki le ti s’aye si o, eyin to di ‘po mu Ki le ti lo’po si, eyin ta gb’ ola fun A sipe e ba wa s’oja yi ko ma la tu mo wa lori A sipe e ba wa w’oja yi naa ko ma la tu mo wa lori o Eyi te ba se la maa ba o aanu ola wa, e je o se yinEro oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo Ero oja olomo Ja lo lo, ja lo lo Eyin agba t’o wa lori ile, ero oja Ja lo lo, ja lo lo Eyin agba t’o wa niwaju, eyin lero oja Ja lo lo, ja lo lo Ki le ti s’oja yi si o? Ja lo lo ja lo lo Ki le ti s’aye si? Ja lo lo ja lo lo Ki le ti s’oja yi naa? Ja lo lo ja lo lo E ma ma je k’oja yi tu mo wa lori Ja lo lo ja lo lo To to se bi imoran, mi o to gba yin ni ‘moran Ja lo lo ja lo lo E w’oja yi na o, e ba wa se k’o da Ja lo lo ja lo lo Nitori ola wa, e ba wa se k’o da Ja lo lo ja lo loIpokipo t’a ba wa, k’a ranti Eni to lemi to fun wa mi
B’agba miran ba soro, a b’omi tutu s’okan mi E je a maa ranti Oba orun to f’ola ran wa ni ‘se s’aye E wo awon omo to wa loke ohun bi won ti n p’ebi mo ‘nu E wo awon eni to wa lapa ibi bi won ti n rare k’aye Ranti Eni to lemi re, ranti Eni nla to le ji, to le pa ni iseju kan O ki ‘yun bo ‘le, o fa ‘yun yo Won ke ‘borun meje, won gbe ‘gba ata Isoro si re, ihuwasi re, ilo ‘po si re, eh eh Ranti Oba to lesan oEro oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo Eyin obi wa, eyin egbon wa to wa niwaju Ja lo lo, ja lo lo Ki le ti s’oja yi si o? Ja lo lo ja lo lo Obiri laye o, ko duro sodo enikan Ja lo lo ja lo lo Eyi to ba se la o royin ranti ola Ja lo lo ja lo lo Ki le ti s’aye si o? Ja lo lo ja lo lo Ki le ti na ‘ja yi si? Ja lo lo ja lo lo E ma ma je k’oja yi tu mo wa lori Ja lo lo ja lo lo E ma ma je k’oja yi tu mo wa lori o o Ja lo lo ja lo lo E w’oja yi na o, e ba wa se k’o da Ja lo lo ja lo lo Nitori ola wa, a bebe, e ba wa se k’o da Ja lo lo ja lo loEbe la be o
Nile loko lodo eyin agba e w’ oja yi na Ko ma baje la n toro Agbara atorun wa a di yin mu o Eleduwa a gba fun wa, Amin o Amin aseEro oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo E gb’ ekun wa ba se n bebe eyin ero oja Ja lo lo, ja lo lo B’aye ti ri yi o da, eyin ero oja Ja lo lo, ja lo lo Ife eleda fun wa ko ni ‘yi o rara Ja lo lo, ja lo lo Nitori ola wa, e w’ ekun wa Ja lo lo ja lo lo B’aye ti ri yi o da o Ja lo lo ja lo lo Ki le ti s’oja yi na? Ja lo lo ja lo lo E ma ma je k’oja yi tu mo wa lori Ja lo lo ja lo lo E ma ma je k’oja yi tu mo wa lori Ja lo lo ja lo lo E ma ma je k’oja yi tu mo wa lori Ja lo lo ja lo lo