Shola Allyson – Ẹ̀bẹ̀ and Prayerś (Live)
Ẹ̀bẹ̀ and Prayerś (Live) by Shola Allyson Mp3 Download +(Video & Lyrics)
Download this track from Shola Allyson titled Ẹ̀bẹ̀ and Prayerś (Live). Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Ẹ̀bẹ̀ and Prayerś (Live) by Shola Allyson
Oh Lord have come to seek ur face
Let your grace and mercy Fall upon me LordOh lord I call upon ur name
Let the rain of ur mercy Fall upon me LordOoooluwa mo wa sibi ite
Jeki ore ofe ati anu re ko balemi Lori Ooooluwa mo ke pe oruko re Jeki ojo anu re ko ro s’ori iseda miBabaaaa oooo eyi lebe
Baba alanu oo Babaaa oooo Olugbebe gbo ebe mi oluwa Eyi l’ebeAyemi kobu ola fun o ni mo bere
Ona mi koto ninu ife re oluwa Oooooooo eyi ni ebeGbami lowo asise oluwa
Gbami lowo Ogun tapa obimi oka Gbami lowo Ogun Iran diran Oluwa gba mioo baba Eeeeyi lebeOluwa towo batinomiu afoju San
Babaaa oooo eeeyi lebe Oba toji oku omo jairu dide Oku lazaru ojo merin otira otin run Iwo loji dide oluwa sanu mi Jesu omo davidi gbo adura mi oluwa Babaaa oooo eeeyi lebe Lord I’ve come to seek ur face Let ur grace and ur mercy Ore ofe tomumi Debi Koma pada leyin mi Come upon me Ooh Lord I call upon ur name Let the rain of ur mercy Fall upon me Lord O ooooluwa Iwo to mumi Debi Wa semi olododo Let the rain of ur mercy Fall upon me Lord Babaaa oooo mo kigbe lohun rara Si o latokun iseda mi oluwa Eeeyi ni lebe Baba alanu Babaaa oooo Ore ofere ni mo bere Aye ose gbe lai so ore ofe re Eeyi lebe Ona maa su ni gbami Nigba ti Ona mi ba su tun imole fun mi Mi o ni fese ko ni irin timohun run Iwo to Mumin Debi ose olododo Latin sun mi siwa ju Eeyi lebe Mogba agbara lowo alagbara pelu agbara re Babaaa oooo eeeyi lebe Ilekun toti kosi Kilo ti ilekun kokuro nibe Ilekun to ti kosi oluwa oo Eeyi lebe Awon towa ni ibi imole ko tan imole Lori iseda mi Babaaa oooo Gbogbo ibi ti okunkun wa Ki imole wole Imole kowole ilekun toti kosi Ilekun toti ko so Kilo ti ilekun, ilekun toti kosi Babaaa oooo Ati rami pada Moti di omo I decree ilekun toti kosi Eeeyi lebeAdi ileri remu
Pewo yio wa pelu awa To gbeke loruko re Adi ileri re mu baba oni leri Ti kin ye Pewo yio wa pelu awa To gbeke lorukore Adi ileri re mu Tani oke ni waju serubabeli Pewo yio wa pelu awa Oba onileri tikin ye Ona abayo lodo re ju egbagbeje lo Ona abayo lodo re ju egbagbeje lo Kiloun ti ilekun Ilekun kosi Adi ilerire mu Babaaa oooo Pewo yio wa pelu awaTo gbeke lorukore
Adi ilerire mu Amope Iwo yio wa pelu awa To gbeke lorukore Oniduro mi ESE oo Oni duro mi ESE oo Alanu mi ese oo Irowo tofun mi ni irowo ese oo To ba se eniyan loduro Eniyan ti makun Boba se eniyan loduro Enyan ati ma saroye Oni duro mi ese oooOniduro mi ESE oo
Oni duro mi ESE oo To ba se eniyan loduro Eniyan ti makun Boba se eniyan loduro Enyan ati ma seregun Oni duro mi ese ooo