Shola Allyson – Ayanimo Ife
Ayanimo Ife by Shola Allyson Mp3 Download + (Lyrics)
Download this track from Shola Allyson titled Ayanimo Ife. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Ayanimo Ife by Shola Allyson
Ololufe wo oju mi
So fun mi p’oo fe mi Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa Ololufe wo oju mi So fun mi p’oo fe mi Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O wa fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore O fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore Owo mi ree, fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa Ayo wa ti d’ajose Ola wa ti d’ajoni Irin wa ti d’ajorin Ibanuje ko jina si wa Wo mi o tun mi wo pel’oju inu Irin wa laye jo’ra won Wo mi o tun mi wo pel’oju inu Irin wa laye jo’ra won Ayanmo wa j’ayanmo Loro ife wa se se regi Ayanmo wa jo ayanmo Loro ife wa se se regi Owo mi ree o fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa Ko le se ki ija ma wa Jowo je a jo s’asoye B’oro ba se bi oro Jowo fi suuru ba mi se Ore okan mi pe mi o bi mi Ogiri wa ko ma a la’nu Ore okan mi pe mi o bi mi Ogiri wa ko ma a la’nu B’aa ba f’imo wa s’okan Oke oke la o ma lo B’aa ba f’imo wa s’okan Oke oke la o ma lo Owo mi ree yi o fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa Ololufe wo oju mi So fun mi p’oo fe mi Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa Ololufe wo oju mi So fun mi p’oo fe mi Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O wa fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore O fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore Owo mi ree, fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa B’afefe idanwo ba fe de Duro ti mi o girigiri B’o ti wu k’oorun mu to Sanmo dudu a wa dandan ni B’afefe idanwo ba fe de Duro ti mi o girigiri B’o ti wu k’oorun mu to Sanmo dudu a wa dandan ni Iwenumo ma lo je, ka tun le r’aanu gba si ni Isoro oni adun ola ni, ayo at’ope lo ma ja si Owo mi ree yi o fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O wa fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore O fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore Owo mi ree, fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O wa fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore O fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore Owo mi ree, fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O f’imole re fun mi O f’agbara mi fun o O wa fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore O fi idanu si’nu wa Lati mo ‘fe, lati mo ore Owo mi ree, fa mi dani Ase Oluwa ni Ayanmo ife la je fun ‘ra wa Lat’odo Eni to da wa