Shola Allyson – Adura Ololufe
Adura Ololufe by Shola Allyson Mp3 Download + (Lyrics)
Download this track from Shola Allyson titled Adura Ololufe. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Adura Ololufe by Shola Allyson
Adura mogba fun e ololufe mi
Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi Oo ni kagbako l’aye oo ni r’ogun akoba Oo ni s’irin l’aye be oo ni t’oju ile mole Ainif’okanbale o ni y’odo re lailailailailai Oo ni m’osi l’aye, aye re a ma dara si Ife eledumare ree e ooo ore mi O fewa fun re, o fewa f’ayo taa ba barawa s’otito Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s’ise Iranse alaanu re wa pelu t’emi nwon njo rin po niIbaase ‘wo layo pupo latagbala eledumare wa inu oluwa aa dun si
Ibaase’ wo layo pupo latagbala Eledumare wa o, inu oluwa aa dun si waOba ni a lowo a bi’mo
Oba ni a s’owo a j’ere Oba ni a r’aje jeun Imole aa ma tan siImoran mi ree fun e ooo oloro mi
Imoran ni mo n gba e ninu ife to jin oloro mi maa gbo Pe ko maa s’ora se, ore mi at’orun s’ora se Jowo f’arabale ko gb’emi olorun l’aye ko M’okan at’eti re kuro ninu etan to kun’nu aye Gbogbo ohun to ma n dan ko ni wura, Joo ma fi ididi w’ola, ola aa to ni wa, Fitila ona re o ni ku lailai, aye re a ma dara si.Owo o ni wan n’ile wa
Owo Olorun nbe lara wa Owo Oluwa nba wa lo Imole a ma tan siOpe ti mo nda l’ojojumo ree ore okan t’eledua fun mi maa gbo
Modupe mo yin’le f’olu to gbe mi pade alaanu Mosope mi o kuta l’oju oja ife, eleda lo ba mi se Alabarin t’eledua yan fun o gangan ni moje Alabase t’olorun fifun mi gangan ni iwo je Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l’ayo, Ka sa maa sora se Ajose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora seOba ni a lowo a bi’mo
Oba ni a s’owo a j’ere Oba ni a r’aje jeun Imole aa ma tan siIfe okan mi ree, ore okan mi tipetipe maa gbo
Pe ka je imole, imole wa ko tan f’araye ri Ka f’ara wa lowo, ka jo rin f’olu, ka nipa rere f’ayo Eni waye lai mu’fe orun se, asan bansa Aa r’owo lo, aa f’ola we, ka s’ise taa ran wa wa pa bi fun Ajose wa a maa mayo wa o nfun wa l’ayo, ka sa maa sora se Ajose wa a maa mayo wa, ka sa maa sora se.Ajose wa a maa mayo wa…
Ka sa maa sora se…