Shola Allyson – Iwo Nikan
Iwo Nikan by Shola Allyson Mp3 Download + Lyrics
Download this track from Shola Allyson titled Iwo Nikan. Sola Allyson-Obaniyi, popularly known as Shola Allyson or Sola Allyson, is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter.
Use this link below to stream and download the track
Lyrics Of Iwo Nikan by Shola Allyson
Iye a wa
Eni to ni iye lodo, a pin temi kan mi o Iye a waIye a wa
Eni to ni iye lodo, a pin temi kan mi o Iye a waIye de
Eni to ni iye lodo, O pin temi kan mi o Iye deIye de
Eni to ni iye lodo, O pin temi kan mi o Iye deO wa ooo, O wa
O de ooo, O de O wa ooo, O wa O de ooo, O deAanu de
Alaanu f’aanu s’aanu, O mu temi ko mi Aanu deAanu de
Alaanu f’aanu s’aanu, O mu temi ko mi Aanu deO de ooo, O de
Isegun wa
Olusegun, Ajasegun, O gbe temi ko mi o Isegun waIsegun de
Olusegun, Ajasegun, O gbe temi ko mi o Isegun deO wa ooo; O wa, O de ooo; O de
Iye a wa
Iye de Eni to ni iye lodo, O pin temi ko mi o Iye de