Enia Lasan – Chief Ebenezer Obey
Enia Lasan by Chief Ebenezer Obey Mp3 Download + Lyrics
Download this track from Chief Ebenezer Obey titled Enia Lasan. Ebenezer Obey began his musical training-cum-career as a member of the school band at Methodist Primary School, Idogo.
Use this link below to stream and download the track.
Lyrics Of Enia Lasan by Chief Ebenezer Obey
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Omoyini Barrister maa binu enikan
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Omoyini Barrister maa binu enikan
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Omoyini Barrister maa binu enikan
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Omoyini Barrister maa binu enikan
Awon abani je won un beru Oluwa
Awon aba teniyan je won un beru Oluwa
Toba se ika tan woni aba a e je kin ri
Ati ibaje elenu eniyan ni won wa
Ekale ma maa gbor kor le mi
Awon aba teniyan je won un beru Oluwa
Toba se ika tan woni aba a e je kin ri
Ati ibaje elenu eniyan ni won wa
Ekale ma maa gbor kor le mi
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Omoyini Barrister maa binu enikan
Awon eyan lasan won ti be yan rere je
Omoyini Barrister maa binu enikan
Oluwa emi sa ti gbohun Re
O nso ti ife Re si mi
Sugbon mo fen de l’apa igbagbo
Kin le tubo sunmo O
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ agbelebu t’O ku
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ eje Re t’o niye
O nso ti ife Re si mi
Sugbon mo fen de l’apa igbagbo
Kin le tubo sunmo O
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ agbelebu t’O ku
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ eje Re t’o niye
Oluwa emi sa ti gbohun Re
O nso ti ife Re si mi
Sugbon mo fen de l’apa igbagbo
Kin le tubo sunmo O
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ agbelebu t’O ku
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ eje Re t’o niye
O nso ti ife Re si mi
Sugbon mo fen de l’apa igbagbo
Kin le tubo sunmo O
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ agbelebu t’O ku
Fa mi mora mora Oluwa
Sib’ eje Re t’o niye
Tiwa tiwa Omoyimiyun Barrister lawyer le omoyin ibimi
Tiwa tiwa Omoyimiyun odi le oloye le baba loje
Tiwa tiwa Omoyimiyun awon Oluwole Peters nle baba lonje
Tiwa tiwa Omoyimiyun awon Antab jeje lowo baba bouncer
Tiwa tiwa Omoyimiyun
Tiwa tiwa Omoyimiyun
Tiwa tiwa Omoyimiyun odi le oloye le baba loje
Tiwa tiwa Omoyimiyun awon Oluwole Peters nle baba lonje
Tiwa tiwa Omoyimiyun awon Antab jeje lowo baba bouncer
Tiwa tiwa Omoyimiyun
Tiwa tiwa Omoyimiyun