Dr. Victor Olaiya – Ewo
Ewo by Dr. Victor Olaiya Mp3 Download
Download this track from Dr. Victor Olaiya titled Ewo. Victor Abimbola Olaiya OON, also known as Dr Victor Olaiya, was a Nigerian trumpeter who played in the highlife style. Though famous in Nigeria during the 1950s and early 1960s, Olaiya received little recognition outside his native country.
Use the link below to stream and download this song.
Lyrics Of Ewo by Dr. Victor Olaiya
To ba fe l’owo ko ma se fo’le, fo’le o (ewa)
To ba fe l’owo ko ma se fo’le (ewa), fo’le o (ewa) fo’le
So gboro mi (ewa), ko ma se ja’ le ore o (ewa)
Kere kere kere o (ewa), kere o kere o (ewa)
L’okunrin l’obirin (ewa), l’omode l’agba o (ewa)
L’okunrin l’obirin (ewa), l’omode l’agba (ewa)
Ohun s’ewa (ewa), ohun t’ewa (ewa)
Ohun s’ewa (ewa), ohun t’ewa (ewa)
Ohun s’ewa (ewa), ohun t’ewa (ewa)
Ohun s’ewa
To ba fe l’owo ko ma se fo’le, fo’le o (ewa)
To ba fe l’owo ko ma se fo’le (ewa), fo’le o (ewa) fo’le
So gboro mi (ewa), ko ma se ja’ le ore o (ewa)
Kere kere kere o (ewa), kere o kere o (ewa)
L’okunrin l’obirin (ewa), l’omode l’agba o (ewa)
L’omode l’agba (ewa)
Ohun s’ewa (ewa), ohun t’ewa (ewa)
Ohun s’ewa (ewa), ohun t’ewa (ewa)
Ohun s’ewa (ewa), ohun t’ewa (ewa ewa)