Chidinma – Osuba
Osuba by Chidinma Mp3 Download+Video,(Lyrics)
Download this track from Chidinma titled Osuba
Use this link below to stream and download the track.
Lyrics Of Osuba by Chidinma
Ato gba rále oooo
Eberu kósi fun mi
Ayá o fo mi ooo Aladé wura olorun tó ga ju Olododo Talo to ó Taloju o lo? Oba mi Eni to mówa Oba to mo wa To mohun gbogboOsuba olorun ijaya
Gbanigbani olorun a n saya Eni to lemi mi, mo dé Osuba olorun ijaya (osuba olorun ijaya) Gbanigbani olorun a n saya Eni to lemi mi mo déOlodumare ooo
Oba akoda ayé ooo Ogbigba ti n gba alailara Asoromayewun ooo O gbeni ni ja Keru o bo onija O pin okun niya O ji òku dide Iba re maa re sir Eleburuike ni ooo Eni to mówa Oba to mo wa To mohun gbogboOsuba olorun ijaya (osuba olorun ijaya)
Gbanigbani olorun a n saya Eni to lemi mi mo dé Osuba olorun ijaya Gbanigbani olorun a n saya Eni to lemi mi mo déOnibu ore ooo
Jagun jagun ode orun oo Oba ti nbe nibi gbogbo Akijuba Apejuba Asajuba Osuba re re Osuba re re Osuba re re ooo