Welcome to PraiseZion



HOME |   |  SERMONS
|  JOBS |  INSTRUMENTAL | MIXTAPES |  DEVOTIONAL

SEARCH CONTENTS (Use Name Or Title)


Christy Essien Igbokwe – IFE

IFE by Christy Essien Igbokwe Mp3 Download

Download this track from Christy Essien Igbokwe titled IFE. She was the first female president of the Performing Musicians Association of Nigeria (PMAN), and the chairwoman and managing director of Soul Train Entertainment.

Use this link below to stream and download track.

Lyrics Of IFE by Christy Essien Igbokwe

E je ka sise po eyin ara mi
Je ka feran ara wa eyin ara mi
Je ka rin po eyin ara mi
Ka maa ni ota l’arin wa eyin ara mi

Ife gbogbo eniyan la n wa o
Fun ile Nigeria
Ija irepo l’oye ka ja
Fun ile Nigeria
Ija irepo l’oye ka ja
Fun ile baba wa o
Ija irepo l’oye ka ja
Fun ile Africa

Ife ife ife ife
Ife ife ife ife

Omo ko ye ko sa f’omo bii ti jaguda ko eah eh
Ara ko ye ko sa f’ara bii ti kuruna ko eah eh
Enu ko ye ko sa f’enu bii ti kokoro ko eah eh

Ife ife ife ife
Ife ife ife ife

E je ka sise po eyin ara mi
E je ka feran ara wa eyin ara mi
E je ka rin po eyin ara mi
Ka maa ni ota l’arin wa eyin ara mi
Ife gbogbo eniyan la n wa o
Fun ile Nigeria
Ija irepo l’oye ka ja
Fun ile Nigeria
Ija irepo l’oye ka ja
Fun ile baba wa o
Ija irepo l’oye ka ja
Fun ile Africa

Ife ife ife ife
Ife ife ife ife

Omo ko ye ko sa f’omo bii ti jaguda ko eah eh
Ara ko ye ko sa f’ara bii ti kuruna ko eah eh
Enu ko ye ko sa f’enu bii ti kokoro ko eah eh

Ife ife ife ife
Ife ife ife ife
Ife ife ife ife
Ife ife ife ife
Ife ife ife

Download Mp3 Here

| Categories: Music

CLICK HERE TO COMMENT ON THIS POST

WE ARE ON SOCIAL MEDIA

Facebook | Twitter | Instagram | Youtube

0 Comments

LEAVE A COMMENT

Type Name Below

Type Comment Below

« | »