Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise
Get this song from Tope Alabi which she titled Loro Lero Ati Nise
Use this link below to Stream and download Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi
Download Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi
Lyrics Of Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi
Verse 1:
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise
Chorus:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Verse 2:
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise
Verse 3:
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise.