Tope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah
Get this song from Tope Alabi which she titled Eyin Oluwa Halleluyah
Use this link below to Stream and download Eyin Oluwa Halleluyah by Tope Alabi
Download Eyin Oluwa Halleluyah by Tope Alabi
Lyrics Of Eyin Oluwa Halleluyah by Tope Alabi
Verse 1:
Eje ka f’ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai
Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah
Verse 2:
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun
Verse 3:
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo
Verse 4:
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo