Pepenazi – The Invisible Ark
Download this track by Pepenazi titled The Invisible Ark. Opeyemi Gbenga Kayode (born 16 April 1988), known by his stage name Pepenazi, is a Nigerian singer and songwriter. He made his debut in the Nigerian music industry in 2012 with the single “Arose”, produced by Bam Tunes.Use the link below to stream and download The Invisible Ark by Pepenazi.
Lyrics of The Invisible Ark by Pepenazi
[Verse]
Olorun ko da bi omo eniyan, eniyan, eniyan, aronipin,
t’eda ba dabi Olorun, oh oh nkan be
Won le nipe, k’ojo ma ro, e den wa ba ile aye je,
e den fe k’oju ija s’olorun, oh oh, eniyan, aronipin
Olorun be loke, asoro ma ye, tori iwo ko lo da mi,
iwo ko lo da mi, ohh eniyan, aronipin
Iwo ko lo da mi, iwo ko la mu mi dahba,
iwo ko lo to mi, olorun lo to mi, aronipin, eku iya oh
Adaba, adaba oh, adaba oh oh, sokale wa
Come and heal the world, come and heal the world,
e ti so ile aye do sodom and gomora ohh, social media eniyan, aronipin
Eniyan, aronipin, eniyan, aronipin, odun tuntun