Sola Allyson – YÓÒ DÁA
Download this song from Sola Allyson titled YÓÒ DÁA. Sola Allyson is a Nigerian soul, folk, and gospel singer and songwriter and also makes music covers for Nigerian movies. Use the link below to stream and download this track.
Lyrics of YÓÒ DÁA by Sola Allyson
Ta l’eni naa ti n sope ko le da, yoo daa
Ta l’eni naa ti n sope ayemi ko le dide mo
Ta l’eni naa to n so wi pe oti tan ooo aaa
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo (igba
meji)
Eni to n mu mi bo lati ipinlemi o ma ga
Oun lo mumi rin, lalai f’ese ko o ma ga
Oun lo mumi duro mi o le subu ooo lai lai
Wo mi k’ori p’alaanu ni baba gan o ma ga
Oun lo n da mi bi adaran nje
Oluso agutan mi
Oun lo n re mi, lo n to isise mi, beeni
Oro re fitila l’ese mi
Imole l’ona mi
Ati pemi wole imole baba, beeni
Ta l’eni naa ti n sope ko le da, yoo daa
Ta l’eni naa ti n sope ayemi ko le dide mo
Ta l’eni naa to n so wi pe oti tan ooo aaa
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo (igba
meji)
Eni ma ri akokoseju, amaagbetidan ni
Inunibini enikan o le pe k’ojo mala ooo
Orun awo bo ti wu k’eletanu f’apajanu
Emi eni imole, omo olorun oga ogo ooo
Ati f’ororo yan mi k’olemi to so nigba yen
Ta l’eni naa ti n sope ko le da, yoo daa
Ta l’eni naa ti n sope ayemi ko le dide mo
Ta l’eni naa to n so wi pe oti tan ooo aaa
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo (igba
meji)
Response
“Wo mi k’ori
Ko lo mo pe yoo da osi ku oo
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo”
Oluwa tosin, oto gbekele,
Oun ni kii doju tini ooo, lai lai
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo
Adani ma gbagbe, alase yori
Agbanilagbatan ni o ma dun gan
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo
Eni ba gbeke l’oluwa ko ni jogun ofo
Oluwa tosin gan
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo
Okan re saare, gboju soke
Ko si ona, gboju soke
Oluwa dun gan
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo
Bo ti wu ko ri, iranwo awa lat’odo oluwa
O po ni aanu ooo
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo
Ma so’reti nu
Bo koro, adun la gbeyin
Oluwa dun gan
Wo mi k’ori p’oluwa ma dun gan, osi po ooo