Bolaji Akeredolu – Olorun Alagbara
Bolaji Akeredolu is a born again, spirit-filled gospel singer and prolific gospel songwriter. She is the convener of WORSHIP WORKS WONDERS (Atmosphere of supernatural encounter) a quarterly worship service where diverse miracles are testified to under the influence of HOLY SPIRIT. She is a minister in The Redeemed Christian Church of God, married and blessed with children.
SOCIAL HANDLES
Facebook: Bolaji Akeredolu Ademokoya
Instagram: worshipworkswonders
Psalm 24:8 Who is this King of glory? The Lord strong and mighty, The Lord mighty in battle. This song “OLORUN ALAGBARA” which translates MIGHTY GOD proclaim the great power and strength of God. It also describes God by title indicative of supremacy over all situations from unfruitfulness to fruitfulness, stagnancy to unlimited breakthroughs. Mighty God is able to do far more than we can even imagine.. Be blessed as you listen in Jesus name.
LYRICS OF “OLORUN ALAGBARA”
Chrs: Olorun tole Olorun to lagbara
Alagbara sa ni oruko Re
Olagbara o lati soro mi dayo
Dasi oro mi kowa gbe mi nija
Egbori yin soke eyin enu ona
Kagbe yin soke ilekun ayeraye o
Ki Oba ogo kowonu ile wa o
Olorun awon omo ogun ni oba ogo
Kosohun tole tokoja Oluwa
Kosi soro to lagbara j’olorun lo
Ogun ipile Oluwa ba o wi
Jade o kowo nu ogbun lo
Egboro Oluwa gbogbo ile omo
Gbogbo okan toni idaduro o
Loruko Jesu ni mo pase fun yin
Ejade o kewo nu ise rere lo
Bridge
Oluwa ran mi nise hallelujah
Iwo ni uno je ise na fun
Ako ninu oro Re hallelujah
P’eni to ba wo Jesu yoo ye
Wo koye arakunrin
Wo Jesu ki osi ye
Ako ninu oro Re Halleluyah
P’eni to ba wo Jesu yoo
Call and Response
Call: Epe loruko tonje
Resp: Olorun awon omo ogun/2x
Welldone ma. More grace
by Anonymous on Oct 24, 2020 at 20:53