Song Mp3 Download: Ebenezer Adeusi – Atobiju
Download gospel song mp3 by Ebenezere Adeusi titled Atobiju. Use the download link below to get this track.
DOWNLOAD SONG HERE
LYRICS
1. Awon kan laye won polorun won ni igi,
Awon kan laye won polorun won ni ookuta,
Awon kan laye won polorun won ni omi,
Sugbon emi n so wipe, iwo ni Atobiju.
2. Olorun alaye ni o o o ki n solorun oku,
Eni o sin o ohun ti o to o ni yoo sin gbeyin o,
Agbara re ga riru okun o tun seyin re,
Iyin re yi aye bee naa lo gbara orun,
Emi n soo wipe iwo ni Atobiju.
3. Atobiju ni Olorun ti gbe nipekun orun,
Atobiju ni Olorun to lo repete lai login,
Atobiju ni igbanla to bori gbogbo ayee,
Emi n so wipe iwo ni atobiju.
4. O lana sori okun lojo yen okun no le gbin peke,
O ti Jericho subu oba Jericho o le soro
Nebukadinesari gan mo o ni atobiju se
Lemi fi n soo wipe iwo ni atobiju.
5. Atobiju ni olorun ti n sohun tenikan o le se
Atobiju ni Olorun to fomi se iti igi aja iyewu
Atobiju ni agbara inu awon imole gbogbo,
Emi so wipe iwo ni ATOBIJU.
Bridge: ki gbogbo aye ki o teriba foba aa
Spokane words: Ki won wole niwaju ite o
Ki gbogbo eda eniyan gbe ohun iyin won soke
Ki awon angeli ti won wa ni ita didan ni gbe ohun iyin soke
Kiyin oloorun didun gun ite baba wa.
Emi so o wipe iwo ni atobiju /2
Gbogbo enu ni mo fi so wipe
All: iwo ni atobiju
Oke nla efohun ogo oo
All: iwo ni atobiju
Lanitan ti n bo gbogbo aye
All: iwo ni atobiju.
YOUTUBE channel
Ebenezer adeusi